Dreams and it's meaning! (Yoruba Version)
ALA PELU ITUMO ATI AWAN ADURA. LATI OWO CHIEF IMAM ALH. TAOFEEQ ELESHINOGO.
Bi oba lala ri Eni (mat). IKU OJIJI nio tumosi.
Bi oba lala wipe Ogbe igbadani. ABURU lotumosi.
Bioba lala nmu OWO nile. IDENA lotumosi.
Bioba lala pe onya igbe loju orun. AISAN lotumosi.
Bioba lala pe onto (urinate) ni oju orun. AISAN ni ojasi.
Bioba lala ri elede ni oju orun. IKORIRA ni lotumosi.
Bioba lala pe onsare (sick) ni oju orun. IDAMU lojasi.
Bi oba lalape owa Lori Eshin funfun. AYO lotumosi.Sugban to bake Eshin dudu. Ewu lojasi.
Bioba lala pe wan yin ni ibon(gun) IJAKULEEMI lotumosi.
Bioba lala pe Onkiri ataloju orun. IDAMU lojasi.
Bioba lala pe onroko loju orun. Aburunla lotumosi.
Bioba lala pe onba iyaworeja loju orun. ADANIDURO lotumosi.
Bioba lala pe okosi konga. Idamu ati wahala lotumosi.
Bioba lala pe obi omo loju orun. ABURUNLA lojasi.
Bioba lala pe owa ninu Moshalasi. Orire lojasi.
Bioba lala pe ohun rerin loju orun. ABURUNI.
Sugban tiobajasipe osunkun jade loju orun. ORIRENI.
Bioba lala se ADURA loju orun. ORIRENI, ADURA yen yiogba.
Bioba lala pe ojo nro. ORIRENI.
Sugban ti ojo Na ba San ara pelu ibinu. ABURU NLANI lotumosi.
Bioba lala pe owa ninu motto tiogbeelo. ABURU NLANI.
Bioba lala pe owani Ihoho. IFI OWOGBEOMOSIN lotumosi.
Bioba lala ri Aja loju orun. ABURUNI.
Bioba lala ri ologbo. ABURUNI.
Bioba lala ri eye ile. ORIRE NLA.
Bioba lala ri Asa. ABURUNI.
Bioba lala se Inawo ti eropo. ABURU aini ri odesini lotumosi.
Bioba lala pe oowo akisa loju orun. IYALOJASI sugbon ireti wa tobasesara.
Bioba lala oowo aso tuntun tabi ra aso tuntun. ABURUNI.
Bioba lala ri ata tabi ra ata tabi lota. IDAMUNLA nitotumosi.
Bioba lala pe ole wajao ni oju Orun. AJALUNLA NI lotumosi.
Bioba lala pe Ilenjo. ISORONLA lojasi.
Bioba lala oje Eran loju orun. EGBEKEGBE lotumosi EGBE AWAN AGBA.
Bioba lala ri Eyin lopolopo. ORIRENI Sugban tiobafo Aburuni.
Bioba lala ri agbado funfun loju orun. ORIRENI.
Bioba lala ri ejo(snake) OYUN tabi ki ota malepa irun enibe.
Bioba lalari posi. AJALUNLA lotumosi.
Bioba lala ri eruku tioso niwajure. ABURUNi Sora fun ija.
Bioba lala pe ohunfa omi ninu kanga. ORIRENI sugban se Sara.
Bioba lala ri itakun koelese. ABURU IDENE ORENI.
Bioba lala ri Malu. OGUN AMONISENI.
Bioba lalari Ewure. Ogun ASENIBANI DARO.
Bioba lalape Ohunba obirin lopo. ABURUNI.
Bioba lala pe Olopa mue. ABURULOJASI.
Bioba lalpe ohunfo loke tio sifi fi arapa. ORIRENI.
Bioba lala pe Ohunfi Eyinrinpada. IFASEYIN lotumosi.
Bioba lala pe owaloke tioso jabosile. AJALUNLA lotumosi.
Bioba lala pe ose igbeyawo leyin tiotawa ni Ile oko. ABURU ISIPOPADA OBIRE lotumosi.
Bioba lala pe filare sonu. IDAMU lojasi.
Bioba lala pe owe ninu odo. ISORNLA NI Sugban tobawe jade. IBORIOTA lotumosi.
Bioba lalari afa. ORIRENI.
Bioba lalari Egunnu. EMIOKUNKUN NBA eloni.
Bioba lala ri ijapa. ISORO ASENIBANIDEBE lotumosi.
Bioba lala ba eniyan je loju orun. AININI ASEYORI sugba tioba Na enina. AYONi lotumosi.
Bioba lala pe wan fi ADA nle loju orun. WAHALA lotumosi.
Bioba lala pe obimo loju orun. IDAMU LORI OMO LOJASI.
Bioba lala pe ose Are (sick) loju orun. IJAKULE EMI lotumosi.
NOFILA BI OBA LALA KALA.
RAKAT 4. SALLAMO 2. FATHIA 1. LORI IDUROKANKAN. KULI HAUZU BIRABI NOSI 33, KULI HUZU BIRABI FALAKI 33 LORI IDURO KAN KAN.
Ise orijoko.
Allahumo soli waselim 101
Astagifirullahi 101
Kilo huwa lahi 101. Allahumo soli waselim 101.
ADURA ISO OLOHUN ATI EMI GIGUN.
ALLAHU YA ALLAHU YA AFEEZ 111.
ALLAHUMO SOLI WASELIM 33.
WAL YAHUDHU IFUSHUMO WAUWA ALIYU LI AZEEM 9.
BISIMILAHI RAMONI RAHEEM. LAKODIJAKUN ROSULU MIN ANFUSIKUN ASISU ALAHI MON ANITUN HARISU ALEEKU BILIMUMINIA RAHUF RAHEEM FAINTWALAHU FAKUL ASIBAYA LAHU LAILAH ILAUWA ALAEHI TAWAKALITU WAHUWA ROBILI ARISHI AZEEM. 11TIMES.
WALA YAHUDHU IFUSIHUMO WAUWA ALIYU LI AZEEM 9.
AOWA PARIRE BAYIPE- ALLAHU YA ALLAHU YA AFFEZ. so mase adua to ni gbogbo ojo Alaruba ni dede ago kan oru. 1am.
ADUA ISEGUN LORI AWAN ALOBOSI.
allahumo soli ala Muhammad 33.
Ya Allah ya Alik 111.
Allahumo farig hami wagami wakuribati kuli imaturi bani Imaa yuaduna robi fala tajiani fil kaomi sooliina 3 times. So waka suratul Nasi. So mase aduayi ni ojo Monday.
ADUA FUN ENI TOBASE BUKATA.
Raka merin
Sallam meji
Fathia kan.
Kuli huwa llahu hadun 50 Lori idurokanka.
Ise orijoko lehin sallamo.
Allahumo soli waselim 100.
Ya lattef 100.
Allahumo soli waselim 100.
Aowa Toro gbogbo nkan ti aba nfe. Pelu Sara.
#Adura gbogbo ni yiogba Aonidamu InshaAllah. Ameeen
ki ni itumo ki eyan ma ba yan sun ni oju orun ati ona abayo
ReplyDeleteKi ni itumo ki ejo ma le yan loju orun sugbon it ko do yan
ReplyDeleteKini itumo ti eewo ba mu enia loju ninu ala
ReplyDeleteMo la ala pe igi iroko nla wu ninu ile mi
ReplyDeleteBi eniyan ba lala ri eja ninu omi, mini itumo re.
ReplyDeleteKini itumo ki Eyan MA le ejo 🐍 loju orun.
ReplyDeleteMini itun Mon ki afun eniyan ni oroka ni Oju orun like someone give u promised ring
ReplyDeletehttps://bythepost.blogspot.com/2017/04/dreams-and-its-meaning-yoruba-version.html
DeleteWhatsApp me 07064492695
DeleteMini itumo ki eniyan Ku loju ala
ReplyDeleteKini itumo ki won fun eniyan ni eja dindin je loju orun
ReplyDeleteKini itumon pe eniyan yagbe ki o si tun fi yepe po
ReplyDeleteItumo ki eyan je eja ni oju orun
ReplyDeleteBi eniyan ba la laa to owo aso ati Bata ti o ti gbo.kini itumo re
ReplyDeleteMo la la wipe modi olopa loju orun ejowo kini itumo re
ReplyDeleteBi eniyan ba la ala ri opolopo owo eyo ni oju orun, kini o tumo si?
ReplyDeleteWhatsApp me 07064492695
DeleteTi eeyan balala pe ohun wo aso soja (army) kini itumo re?
ReplyDeleteTi eniyan ba la ala pe oun wa moto, break re fail sugbon ko pa eni kankan.
ReplyDeleteKini itumo ala pe,oun ati omo school to won wo uniform wa nidi konga ti won pomi fun
ReplyDeleteWhatsApp me 07064492695
DeleteKoddaa
DeleteTi eniyan ba la ala pe ohun ji ohun Kan ri nkan fun ni Ara ohun nko ..sugbon ti ko la ala rara
ReplyDeleteWhatsApp me 07064492695
DeleteKini itumo ki eyan bi awon omo igbin topo han loju ala
ReplyDeleteTi eniyan ba lala wipe oya igbe sara loju orun
ReplyDeleteTi won ba fun eniyan ni motto Loju orun kini itumo re
ReplyDeleteTi eniyan ba la.alape ounsha igbin loju Orun.kini itumo re
ReplyDeleteTi eniyan ba lala pe oun nje pako loju ala
ReplyDelete