The Power Of Bismillahi in Yoruba version
IWULO BISMILLAHI RAHMONI RAHEEM FUN ADUA
بسم الله الرحمن الرحيم
Eyi ni die ninu ona ti angba lo bismillahi rahmoni raheem awon oruko Olohun meta to lagbara lo pamo si ara gboloun yi akoko ni (Allah الله )elekeji ni (Arahmon الرحمن) iketa ni (Araheem الرحيم) kowa si eyiti afibe Olohun ninu awon oruko yi ti koni gbo.
Jaabir ikan ninu awon sabe Anabi muhammad (saw) Aanu ati ike Olohun fun un) O sope nigbati "BISMILLAHI" sokale, Kurukuru oju orum di ohun ti O ka kuro, Afefe di ohun ti O fi arabale, Awon odo di ohun ti o dake roro, Esu (Saytaani) si di eniti a de mole, leyin eyi ni Allah wa se ileri pe: Eniyiowu ti o ba bere idawole re pelu gbolohun yi:- Bismillahi rahmoni roheem
Mo ni lati fi ibukun ati Alubarika si nkan naa.
(SISAN GBESE )
Bismillahi rahmoni roheem (786)
Yaa Dayaanu (313)
Asibunallahu wanimoli wakilu (33)
Allahumo soli ala seyidina muhammod (100)
Ao mase ni eyin irun Asuba ati ishahi
(FUN IYONU ATI LATIDI ENI APONLE)
Bismillahi rahmoni roheem (786)
Bimo gafarali Rabbi waja' alani minali mukramiina (41)
Falamoo rahaenahu akibarinahu wa qota'ana aediyahuna wa qulina hasa lillahi ma hadha basharu in hadha illaa malakun kareemu (11)
Ao Mase leyin irun asuba abi suhri
Allahumo soli ala seyidina muhammod (100)
(FUN ISOYE ATI ASEYEGE NINU IDANWO)
Bismillahi rahmoni roheem (786)
Sanuquri uka fala tansa (111)
Robbi zidni ilimon (111)
Robbi isirahali sodri wa yasirili amuri wahaluli ukudata min lisani yafu-qohuu qaolii (9 fun okunrin 7 fun obinrin)
Allahumo soli ala seyidina muhammod (100)
Ao Mase ni ekan lojumo abi ki amase sinu omi ojo omi okun tabi omi kanga idaji abi omi odo tonsan daada ao mamu pelu oyin gidi
( FUN ASHINA ATI ITAJA AWORO)
Bismillahi rahmoni roheem (786)
Afuwaajan (450)
Yaatiiha riziquhaa rogadan min kulli mokaani (41)
Wamoo taofiiqi illaa billahi (41)
Allahumo soli ala muhammadi wa Selim (100)
Ao Mase adua yi ni inu shop wa abi ibiti atin sise ao sima fi iyo Suger ati owo se saara
atun lese sinu omi kia afi iyo die si kia fan sibi itaja wa
(FUN ENI TONWA OMO ALALUBARIKA)
Bismillahi rahmoni roheem (786)
Wa waalidin wamo walada (313)
Lamu yalid walamu yuulad (313)
Robbi laa tadharini faridan wa anta khaeru-li- waalidin (11)
Allahumo soli ala muhammadi wa Selim (100)
Ao mafi ounje se saara fun awon ti ebinpa abi onibara
(FUN IWOSAN ABI ADUA LASIKO ADANWO)
Bismillahi rahmoni roheem (786)
Yaa sallamu saliimunii (313)
Salamu qaola min robi roheem (41)
Inii mosaniya duruu wa anta arihamu rahemiina (21)
Allahumo soli ala muhammadi wa Selim (100)
Ao fi ounti abani lagbara se saara Ale se adua yi sinu Zaetun abi epo ogere ki amafi pa Alaisan Lara
(FUN GBIGBO BUKATA ORISIRISI LODO ALLAH WIBE JEBE)
Bismillahi rahmoni roheem 12,000
Ti abati se egberun kan 1,000 ao se adua yi :-
WAMO NASIRU ILLA MIN INDI LLAHI (100)
Ao mase adua yi nibi (egberun kokan 1000) titi yio fi pe (egberun mejila 12,000) ao wafi Robana yi se adua ipari e :-
ROBBANA ATINA MIN LADUNKA RAHMOTA WA HAYYI LANAA MIN AMURINA RASHADAA (11)
Oru ni adua yi daraju lati mase alese fun ojo 3,7,11,21,abi 41 days ao fi pali suger ati owo se Sara re
AKIYESI PATAKI :- Bismillahi rahmoni roheem ni agbara pupo ninu awon oruko Olohun Allah tojepe eniti o ba dunni mo aburu kankan o ni se iru enibe.
O dara ki ama wi Bismillahi rahmoni roheem siwaju ki ato se ohun kohun lapejuwe ti abafe mumi abi afe jehun abi afe sun abi afe pa inkan elemi bi adie eran ati bebe lo abi afe bere Ise abi afewo Inu ile ati bebelo
Plz share for other muslim
ALLAH AGBA ADUA GBOGBO WA AMIN
Jazakallahu Khairan
ReplyDelete