Dreams and it's meaning! (Yoruba Version)
ALA PELU ITUMO ATI AWAN ADURA. LATI OWO CHIEF IMAM ALH. TAOFEEQ ELESHINOGO. Bi oba lala ri Eni (mat). IKU OJIJI nio tumosi. Bi oba lala wipe Ogbe igbadani. ABURU lotumosi. Bioba lala nmu OWO nile. IDENA lotumosi. Bioba lala pe onya igbe loju orun. AISAN lotumosi. Bioba lala pe onto (urinate) ni oju orun. AISAN ni ojasi. Bioba lala ri elede ni oju orun. IKORIRA ni lotumosi. Bioba lala pe onsare (sick) ni oju orun. IDAMU lojasi. Bi oba lalape owa Lori Eshin funfun. AYO lotumosi.Sugban to bake Eshin dudu. Ewu lojasi. Bioba lala pe wan yin ni ibon(gun) IJAKULEEMI lotumosi. Bioba lala pe Onkiri ataloju orun. IDAMU lojasi. Bioba lala pe onroko loju orun. Aburunla lotumosi. Bioba lala pe onba iyaworeja loju orun. ADANIDURO lotumosi. Bioba lala pe okosi konga. Idamu ati wahala lotumosi. Bioba lala pe obi omo loju orun. ABURUNLA lojasi. Bioba lala pe owa ninu Moshalasi. Orire lojasi. Bioba lala pe ohun rerin loju orun. ABURUNI. Sugban tiobajasipe osunkun jade loju orun. ORIREN...