IWULO BISMILLAHI RAHMONI RAHEEM FUN ADUA بسم الله الرحمن الرحيم Eyi ni die ninu ona ti angba lo bismillahi rahmoni raheem awon oruko Olohun meta to lagbara lo pamo si ara gboloun yi akoko ni (Allah الله )elekeji ni (Arahmon الرحمن) iketa ni (Araheem الرحيم) kowa si eyiti afibe Olohun ninu awon oruko yi ti koni gbo. Jaabir ikan ninu awon sabe Anabi muhammad (saw) Aanu ati ike Olohun fun un) O sope nigbati "BISMILLAHI" sokale, Kurukuru oju orum di ohun ti O ka kuro, Afefe di ohun ti O fi arabale, Awon odo di ohun ti o dake roro, Esu (Saytaani) si di eniti a de mole, leyin eyi ni Allah wa se ileri pe: Eniyiowu ti o ba bere idawole re pelu gbolohun yi:- Bismillahi rahmoni roheem Mo ni lati fi ibukun ati Alubarika si nkan naa. (SISAN GBESE ) Bismillahi rahmoni roheem (786) Yaa Dayaanu (313) Asibunallahu wanimoli wakilu (33) Allahumo soli ala seyidina muhammod (100) Ao mase ni eyin irun Asuba ati ishahi (FUN IYONU ATI LATIDI ENI APONLE) Bismillahi rahmoni roheem (786) ...
Comments
Post a Comment